Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà yóò Buwọ́lu Àdéhùn mẹ́wàá Pẹ̀lú Orílẹ̀-èdè Portugal

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Orílẹ̀-èdè Portugal ti ṣètò láti fọwọ́ sí ìwé àdéhùn mẹ́wàá àti ìwé òye lakòókò ìbẹ̀wò Ààrẹ Muhammadu Buhari sí Orílẹ̀-èdè Europe. Ààrẹ Buhari sọ èyí ní ọjọ́bọ̀, ní àpèjọ àpapọ̀ pẹ̀lú Ààrẹ Marcela Rebelo de Sousa ti Orílẹ̀-èdè Portugal.   Ọláyinká Akíntọ́lá.

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà yóò Buwọ́lu Àdéhùn mẹ́wàá Pẹ̀lú Orílẹ̀-èdè Portugal

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Orílẹ̀-èdè Portugal ti ṣètò láti fọwọ́ sí ìwé àdéhùn mẹ́wàá àti ìwé òye lakòókò ìbẹ̀wò Ààrẹ Muhammadu Buhari sí Orílẹ̀-èdè Europe.

Ààrẹ Buhari sọ èyí ní ọjọ́bọ̀, ní àpèjọ àpapọ̀ pẹ̀lú Ààrẹ Marcela Rebelo de Sousa ti Orílẹ̀-èdè Portugal.

 

Ọláyinká Akíntọ́lá.