Orílẹ̀-èdè Israel ti yan Alákòóso tuntun

Yair Lapid ti di Alákòóso Orílẹ̀-èdè Israel, ó gba ipò yìí láti ọwọ́ Alákòóso Naftali Bennett lẹ́hìn ọdún kan. Ọ̀gbẹ́ni Lapid, olórí ẹgbẹ́ ààrin kan, yóò darí orílẹ̀-èdè náà di igba ti ètò ìdìbò yóò wáyé ní ọjọ́ kíní, oṣù kọkànlá. Ìdìbò tí ńbọ̀ yìí ni yóò jẹ́ ìkarùn-ún tí Orílẹ̀-èdè Israel máa ṣe láàrín […]

Orílẹ̀-èdè Israel ti yan Alákòóso tuntun

Yair Lapid ti di Alákòóso Orílẹ̀-èdè Israel, ó gba ipò yìí láti ọwọ́ Alákòóso Naftali Bennett lẹ́hìn ọdún kan. Ọ̀gbẹ́ni Lapid, olórí ẹgbẹ́ ààrin kan, yóò darí orílẹ̀-èdè náà di igba ti ètò ìdìbò yóò wáyé ní ọjọ́ kíní, oṣù kọkànlá.

Ìdìbò tí ńbọ̀ yìí ni yóò jẹ́ ìkarùn-ún tí Orílẹ̀-èdè Israel máa ṣe láàrín ọdún mẹ́rin.

 

Ọláyinká Akíntọ́lá.