Iya Rainbow di ònílé tuntun, ilé méjì ni wọ́n fi ta á lọ́rẹ

0
755

Agba osere ‘binrin, Idowu Phillips, ti ọpọ eeyan mọ si Iya Rainbow tun ti di onile tuntun.Ọsẹ to kọja ni osere naa kede loju opo Instagram rẹ pe ileesẹ kan lo fi ile fulaati meji ta oun lọ rẹ ni agbegbe Mowe, nipinlẹ Ogun.Koda, o ni wọn tun fi orukọ oun sọ opopona kan ninu esiteeti aladani naa.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.