Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣojú ṣe ìfilọ́lẹ̀ Ìgbìmọ̀ Lórí síso Àwọn ilé-iṣẹ́ Ìjọba pọ̀

Ilé-̀ìgbìmọ̀ Aṣojú lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti ṣe ìfílọ́lẹ̀ ìgbìmọ̀ pàjáwìrì kan láti ṣe ìwádìí Ìṣẹ́pọ̀ àwọn iṣẹ́  ilé-iṣẹ́  ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Olori ile igbimọ aṣoju, Hon. Fẹmi Gbajabiamila, ẹni ti o ṣe ifilọlẹ igbimọ naa, sọ pe igbimọ naa ni erongba wọn ni lati din iye owo isejọba ku, ati lati dena aṣeju. O sọ […]

Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣojú ṣe ìfilọ́lẹ̀ Ìgbìmọ̀ Lórí síso Àwọn ilé-iṣẹ́ Ìjọba pọ̀

Ilé-̀ìgbìmọ̀ Aṣojú lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti ṣe ìfílọ́lẹ̀ ìgbìmọ̀ pàjáwìrì kan láti ṣe ìwádìí Ìṣẹ́pọ̀ àwọn iṣẹ́  ilé-iṣẹ́  ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Olori ile igbimọ aṣoju, Hon. Fẹmi Gbajabiamila, ẹni ti o ṣe ifilọlẹ igbimọ naa, sọ pe igbimọ naa ni erongba wọn ni lati din iye owo isejọba ku, ati lati dena aṣeju.

O sọ pe, ijọba ti ṣe akiyesi pe awọn ile-iṣẹ ijọba kan wa ti wọn n ṣe iṣe kannan, eyi ti o fa airisẹ ṣe.