Ikọ̀ agbábọ̀ọ̀lù U-17 tó jáwé olúborí nínú ìdjíje ife àgbáyé pàdé ààrẹ Bujari ní Portugal
Ní ìfihàn ààmì ìfẹ́ rẹẹ̀ sí àwọn eré ìdárayá ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ààrẹ Muhammadu Buhari gba ẹni tó jáwé olúborí ife àgbáyé U17 ní ọdún 2013, Savior Godwin lálejò,ó sì fún ààrẹ ní aṣo ní orílẹ̀-èdè Portugal. Ààrẹ, tí ó lọ sí Ìlú Portugal fún àbẹ̀wò pẹ̀lú Mínísítà Ìdárayá Sunday Dare, pàdé Casa Pia asájú […]


Ní ìfihàn ààmì ìfẹ́ rẹẹ̀ sí àwọn eré ìdárayá ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ààrẹ Muhammadu Buhari gba ẹni tó jáwé olúborí ife àgbáyé U17 ní ọdún 2013, Savior Godwin lálejò,ó sì fún ààrẹ ní aṣo ní orílẹ̀-èdè Portugal.
Ààrẹ, tí ó lọ sí Ìlú Portugal fún àbẹ̀wò pẹ̀lú Mínísítà Ìdárayá Sunday Dare, pàdé Casa Pia asájú ní orílẹ̀-èdè Europe pẹ̀lú alága àwọn ọmọ Nàìjíríà ní ìlú mìíràn, Abike Dabiri-Erewa.
Ọláyinká Akíntọ́lá.