Àwọn Gómìná àti àwọn olórí ẹkùn Àríwá-ìwọ̀ oòrùn ẹgbẹ́ òṣèlú APC pàdé ẹni tí ógbé àsìà Ààrẹ ẹgbẹ́.

Àwọn Gómìná àti àwọn olórí ẹkùn Àríwá-ìwọ̀ oòrùn ti ẹgbẹ́ òṣèlú  All Progressive Congress, (APC) ti pinnu láti fi tó olùdíje ipò Ààrẹ ti ẹgbẹ́, Ọ̀gbẹ́ni Bola Tinubu létí lóri àwọn ọ̀rọ̀ tí ó ní ànfààní sí agbègbè náà. Igbákejì alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC ní ẹkùn àríwá ìwọ̀ oòrùn, Salihu Lukman ló sọ èyí di […]

 Àwọn Gómìná àti àwọn olórí ẹkùn Àríwá-ìwọ̀ oòrùn ẹgbẹ́ òṣèlú APC pàdé ẹni tí ógbé àsìà Ààrẹ ẹgbẹ́.

Àwọn Gómìná àti àwọn olórí ẹkùn Àríwá-ìwọ̀ oòrùn ti ẹgbẹ́ òṣèlú  All Progressive Congress, (APC) ti pinnu láti fi tó olùdíje ipò Ààrẹ ti ẹgbẹ́, Ọ̀gbẹ́ni Bola Tinubu létí lóri àwọn ọ̀rọ̀ tí ó ní ànfààní sí agbègbè náà.

Igbákejì alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC ní ẹkùn àríwá ìwọ̀ oòrùn, Salihu Lukman ló sọ èyí di mímọ̀ nínú àtẹ̀jáde kan lẹ́yìn ìpàdé àwọn gómìná, àwọn olùdíje gómìná àti mínísítà tó wáyé ní ìpínlẹ̀ Kaduna.

 

Ọláyinká Akíntọ́lá.