Ààrẹ Guinea Bissau di alágaa àjọ ọrọ̀-ajé àwùjọ adúláwọ̀

Wọ́n ti yan Ààrẹ Umaro Sissoco Mbalo orílè-èdè Guinea ní ọjọ́ Àìkú gẹ́gẹ́ bí Alágaa tuntun àwọn ààrẹ orílè-èdè ti Àjọ ọrọ̀-ajé àwùjọ iwọ̀-oòrùn Adúláwọ̀,ECOWAS. Alaga  Ajọ ti n lọ, Aarẹ Nana Akufo-Addo orilẹ-ede Ghana, kede eyi ni ipari Ipade ajọ eleekọkan-le-lọgọta  ẹgbẹ agbegbe ni Accra. Alaga ECOWAS tuntun, Mbalo, bori ifipa gbajọbani oṣu keji […]

Ààrẹ Guinea Bissau di alágaa àjọ ọrọ̀-ajé àwùjọ adúláwọ̀

Wọ́n ti yan Ààrẹ Umaro Sissoco Mbalo orílè-èdè Guinea ní ọjọ́ Àìkú gẹ́gẹ́ bí Alágaa tuntun àwọn ààrẹ orílè-èdè ti Àjọ ọrọ̀-ajé àwùjọ iwọ̀-oòrùn Adúláwọ̀,ECOWAS.

Alaga  Ajọ ti n lọ, Aarẹ Nana Akufo-Addo orilẹ-ede Ghana, kede eyi ni ipari Ipade ajọ eleekọkan-le-lọgọta  ẹgbẹ agbegbe ni Accra.

Alaga ECOWAS tuntun, Mbalo, bori ifipa gbajọbani oṣu keji ọdun yii.