Ààrẹ Buhari baalẹ̀ sí ìlú Abuja Láti orílẹ̀-èdè Portugal

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Muhammadu Buhari ti padà sí olú-ìlú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Abuja, lẹ́hìn tó lo ọjọ́ mẹ́rin ní Portugal fún àbẹ̀wò. Ààrẹ baaalẹ̀ sí pápákọ̀ òfurufú Nnamdi Azikiwe ní àṣálẹ́ Sátidé ní Abuja nípasẹ̀ Mínísítà olú-ìlú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Mohammed Bello, àti olóyè òṣìṣẹ́ sí Ààrẹ, ọ̀jọ̀gbọ́n Ibrahim Gambari. Ọláyinká Akíntọ́lá.

Ààrẹ Buhari baalẹ̀ sí ìlú Abuja Láti orílẹ̀-èdè Portugal

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Muhammadu Buhari ti padà sí olú-ìlú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Abuja, lẹ́hìn tó lo ọjọ́ mẹ́rin ní Portugal fún àbẹ̀wò.

Ààrẹ baaalẹ̀ sí pápákọ̀ òfurufú Nnamdi Azikiwe ní àṣálẹ́ Sátidé ní Abuja nípasẹ̀ Mínísítà olú-ìlú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Mohammed Bello, àti olóyè òṣìṣẹ́ sí Ààrẹ, ọ̀jọ̀gbọ́n Ibrahim Gambari.

Ọláyinká Akíntọ́lá.